
Ní ìgbà pípẹ́ sẹ́yìn, Ẹlẹ́dàá rán áńgẹ́lì kan láti ṣe ìbẹ̀wò sí àwọn ẹranko. Áńgẹ́lì náà ní kí àwọn ẹranko béèrè ohun kan, wọ́n sì bèèrè ohun kan tó dà bíi pé kò ṣeé ṣe. Àmọ́, níwọ̀n bí ó ti jẹ́ pé Ẹlẹ́dàá ti ṣe ìlérí pé òun máa mú ìfẹ́ wọn ṣẹ, Ó pinnu láti ṣe bẹ́ẹ̀ fún wọn. Báyìí o, àwọn ẹranko náà ní ojúṣe láti jẹ́ kí ìfẹ́ wọn wá sí ìmúṣẹ, bí bẹ́ẹ̀ kọ́ wọn yóò pàdánù àǹfààní tí kò lè wáyé ju ẹ̀ẹ̀kan ní ayérayé.
Long ago, the Creator sent an angel to visit the animal kingdom. The angel asked the animals to make a wish, and they wished for something seemingly impossible. However, since the Creator had promised to grant their wish, He decided to honor it. Now, it was up to the animals to make their wish come true, or they would miss out on this once-in-an-eternity opportunity.
##ebeyiileju