Biba Jesu Soro: Asa Adura Ojoojumo Fun Awon Omode
Read Online

Biba Jesu Soro: Asa Adura Ojoojumo Fun Awon Omode

(0 Ratings)
1
$5.00

Ṣé ẹ fẹ́ kọ́ àwọn ọmọ yín láti ní ìbáṣepọ̀ pẹ̀lú Jésù, kí wón sì jẹ́ kí àdúrà di àṣà ojoojúmọ́ fún wọ́n lati kékeré?

Bíbá Jésù Sọ̀rọ̀: Àṣà Àdúrà Ojoojúmọ́ Fún Àwọn Ọmọdé jẹ́ ìwé Kristẹni tó lè ràn àwọn ọmọ yín lọ́wọ́, láti omo owó sí odún mewa

(0 sí 10), láti kọ́ bí wón ṣe lè bá Jésù sọ̀rọ̀ ní èdè Yorùbá.

Ìwé ìgbàgbọ́ yìí dára fún ìdílé onígbàgbọ́, àwọn òbí, àwọn olùkọ́ ní ilé-ìjọsìn àti àkókò ìtàn ni ilé-ìwé alakọ́bẹrẹ.


Would you like to teach your kids how to talk to Jesus, and make prayer a part of their everyday life?

Talking with Jesus: Making Prayer a Habit for Kids is a Christian picture book that helps children, ages 0–10, learn to pray in Yoruba language.

This faith-based prayer book is perfect for Christian parents, grandparents, Sunday school teachers, and preschool storytime. 


Frequently bought together

© 2026 Damilola C. Kadiri. All Rights Reserved.

Powered By