
This course is for children, youths and adults who want to learn how to write and read both Yoruba Language and English Language. I will be your teacher and will accommodate and treat accordingly any question from you. This course is for only few lucky people young or old . I will start from letters of the alphabet and teach you untill you are able to read and write.
Idanileko yi wa fún ọmọdé, ọdọ ati agbalagba to fe kẹkọọ lóríi bi a se nkọ tabi bi a se n ka èdè Yorùbá ati ede Geesi, èmi ni n o ma ṣe idanileko náà fún ọ. N o gba ọ laye lati béèrè ìbéèrè n o sí dahùn ìbéèrè rẹ bi ọ ti to ati bi ọ ti yẹ. Idanileko yi wa fún ìwọnba eniyan perete, àwọn tí kò bá jafara láàrin àwọn ọmọdé tàbí àgbà. N o bẹrẹ idanileko yi lati ori alifabẹẹti titi di igba ti óò lé ka èdè Gèésì àti èdè Yorùbá.
É ṣe.
Thanks.
My name is Ajakaye Ezekiel
Orúkọ mi ni Ajakaye Ezekiel