Yorùbá Yé Mi (Apá Kínní)
Downloadable

Yorùbá Yé Mi (Apá Kínní)

(0 Ratings)
1
$3.00

ABOUT THE BOOK

Yorùbá Yé Mi (Apá Kínní) is an important book for understanding the basics of the Yorùbá language. The alphabets of the language, the types (consonants and vowels), along with syllables and how to form words, are also included in the book.

This book covers the essential topics that make up sentences in the language, viz: nouns, verbs, pronouns, conjunctions, and adverbs. Most importantly, it comprehensively explains these topics and offers numerous exercises to ensure a complete understanding of them. Numbers in the Yorùbá language and how to write them from one (1) up to a million (1,000,000) are also included in this part.

This book is suitable for both primary and secondary school students.


➡️ You can get the second part of this book 📙 by clicking HERE.


NÍPA ÌWÉ NÁÀ

Yorùbá Yé Mi (Apá Kínní) jẹ́ ìwé pàtàkì fún ìbẹ̀rẹ̀ ẹ̀kọ́ èdè Yorùbá. Nínú rẹ̀ ni a ti rí Álífábẹ́ẹ́tì Èdè Yorùbá pẹ̀lú oríṣi álífábẹ́ẹ́tì tí a ní. Sílébù àti síso ọ̀rọ̀ papọ̀ kò gbẹ́yìn. Ìwé yìí kún fún àwọn orí-ọ̀rọ̀ pàtàkì tó jẹ́ kókó nínú ìhun gbólóhùn èdè Yorùbá bíi: ọ̀rọ̀-orúkọ, ọ̀rọ̀-ìṣe, ọ̀rọ̀-arọ́pò orúkọ, ọ̀rọ̀-àsopọ̀ àti ọ̀rọ̀-àpọ́nlé.

Pabanbarì rẹ̀ ni pé, ìwé yìí ní àlàyé kíkún àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ ṣíṣe tí yóò fi ìmọ̀ àwọn orí-ọ̀rọ̀ wọ̀nyí múlẹ̀. Òǹkà Yorùbá àti bí a ṣe leè kọ wọ́n láti oókan (1) títí dé àádọ́ta ọ̀kẹ́ (1,000,000) wà nínú apá kínní yìí bákan náà.

Ìwé yìí dára fún àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé alákọ̀bẹ̀rẹ̀ àti girama.


➡️ O leè ra Apá Kejì ìwé 📙 yìí nípa títẹ IBÍ YÌÍ.

Frequently bought together

© 2026 The John Adeh. All Rights Reserved.

Powered By